Episodios

  • 68. "O ru ládugbó ò nrerá; kí ni ká so féni tó ru Òrìsà-a Yemoja?"
    Jul 29 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • ó di ojó alé k’ábuké tó mò pé iké kì í somo.
    • O kò mo èwà lónje à-je-sùn.
    • ò nje àgbònrín èsín lóbè, o ní o ti tó tán.
    • O ru ládugbó ò nrerá; kí ni ká so féni tó ru òrìsà-a Yemoja?

    Support the show

    Más Menos
    13 m
  • 67. "Ó bó lówó iyò, ó dòbu."
    Jul 15 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Nígbàtí à nto okà a ò to ti emó si.
    • Nígbàtí o mò-ó gùn, esin e-e se sé orókún?
    • Nígbàwo làpò ekùn-ún di ìkálá fómode?
    • ó bó lówó iyò, ó dòbu.
    • O dájú dánu, o ò mo èsán mèsán-án.

    Support the show

    Más Menos
    24 m
  • 66. "Níbo lo forúko sí tí ò njé Làmbòròkí?"
    Jul 1 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • “Mo mòwòn ara-à mi” kì í sèrèké èébú.
    • “Mo yó” njé “mo yó,” “mo kò” njé “mo kò;” jeun nisó, àgbà òkánjúwà ni.
    • Ng ó gba owó-ò mi lára sòkòtò yìí; ìdí àgbàlagbà nsí sílè.
    • Nlánlá lomo abuké ndá; ó ní “ìyá ìyá, òun ó pòn.”
    • Níbo lo forúko sí tí ò njé Làmbòròkí?

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Más Menos
    11 m
  • 65. "“Mo mò-ó gún, mo mò-ó tè,” niyán ewùrà-á fi nlémo."
    Jun 17 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • “Mo gbón tán, mo mòràn tán,” kì í jé k í agbón lóró bí oyin.
    • “Mo mò-ó gùn” lesin ndà.
    • “Mo mò-ó gún, mo mò-ó tè,” niyán ewùrà-á fi nlémo.
    • Mo mò-ó tán,” l’Orò-ó fi ngbé okùnrin.
    • Mo m’òbàrà mo m’òfún,” kì í jé kí àwòko kó òpéèré nífa.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Más Menos
    15 m
  • 64. "Mélòó l’èjìgbò tí òkan è njé Ayé-gbogbo?"
    Jun 3 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Mànàmáná ò séé sun isu.
    • “Bí mbá wà l’óyòó mà ti so esin;” àgùntàn-an rè á níye nílèyí.
    • Mélòó l’èjìgbò tí òkan è njé Ayé-gbogbo?
    • Mo dàgbà mo dàgó, eré omodé ò tán lójúù mi.
    • “Mo dára, mo dára,” àìdára ní npèkun è.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Más Menos
    14 m
  • 63. "Lásán kó là n dé etù; ó ní eni tórí è mbá etù mu."
    May 20 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Lásán kó là n dé etù; ó ní eni tórí è mbá etù mu.
    • Lékèélékèé ò yé eyin dúdú; funfun ni wón nyé eyin won.
    • Má tèé lówó oníle, má tèé lówó àlejò; lówó ara eni la ti nté.
    • Màlúù ò lè lérí níwájú esin.
    • Láká-nláká ò séé fi làjà; omo eégún ò séé gbé seré.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Más Menos
    16 m
  • 62. "Kò-sí-nílé kì í jagun enu tì."
    May 6 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kò-sí-nílé kì í jagun enu tì.
    • Kó-tán-kó-tán lajá nlá omi.
    • Labalábá fi ara è wéye, kò lè se ìse eye.
    • Lágbájá ìbá wà a di ìjímèrè; eni tó bá níwájú di oloyo?
    • Láká-nláká ò séé fi làjà; omo eégún ò séé gbé seré.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Más Menos
    15 m
  • 61. "Kò sí mi lájo àjo ò kún: ara è ló tàn je."
    Apr 29 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kíjìpá laso òle; òfì laso àgbà; àgbà tí ò ní tòfì a rójú ra kíjìpá.
    • Kò rà, kò lówó lówó, ó nwú tutu níwájú onítumpulu.
    • Kò séni tó dùn mó, àforí eni.
    • Kò sí mi lájo àjo ò kún: ara è ló tàn je.
    • Kò sí ohun tí Sàngó lè se kó jà léèrùn.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Más Menos
    16 m